Tope Alabi ‘Mimo Loluwa Oba Ara’ [ MP3 + Lyric]

Spread the love

Download Mp3 + Lyrics : Mimo Loluwa Oba Ara By Tope Alabi

Nigerian indigenous gospel singer, Tope Alabi released this amazing glorifying mp3 sound in her tribal language titled Mimo Loluwa Oba Ara.

So too, Mimo Loluwa Oba Ara by Tope Alabi is such an amazing you should afford to listen to as it is been a blessing to many individuals

Thus, kindly click below to stream and download Mp3 of Mimo Loluwa Oba Ara by Tope Alabi with Lyrics provided to sing alongside below

Tope Alabi Mimo Loluwa Oba Ara

DOWNLOAD HERE

Tope Alabi Mimo Loluwa Oba Ara Lyrics

Mimo Loluwa
Mimo
Angeli won mi ke
Awon orun mi ke
Mimo
Egbageje irawo
Mimo
Mimo Loluwa
Mimo
(Angeli won mi ke)
(Awon orun mi ke)
Mimo
Egbageje irawo
Mimo

See Also : Watimagbo By Elijah Daniel Ft Testimony Jaga X Mike Abdul

Agbagba merinlelogun
Lorigun meririn aye o
Atoke atile
Mimo
Se ni won ke tantan o
Mimo
Ta ni yo gori oke oluwa
Mimo
Tabi tani yo duro nine
Mimo
Kabiyesi eledumare oba mimo
Oba nla gbogbo aye e teriba fun oba adari hurun
Oba to ni emi inu eniyan pata
Onikokoro aye lowo
Adagagodo emi gbogbo eniyan
Olukangun orun, ajosun edumare
Jigbinigbin, awu wo bi ate ileke mimo
Opa tinrin kanle o kan orun
Ajosun edumare, minimini ojo to njara o deyan mimo
Orun wawa nigba to padapo sipo
Olorun to sosupa dale torutoru
Oba toun soun gbogbo lasiko lasiko
Oba to le feyin eni ti, ta le feyin eni ti laelae are nla oga tenikan o bi
To bimo Kari aye porogodo
Olowori gbogbo aye  orogodigo baba awon eru
Mimo mimo

 • See Also : I Get Backing By Victoria Orenze
 • Oniwa funfun oba adake se in
 • Ojo fo ke bi ko ye ge re
 • Tenikan o le se un si
 • Ninu ogo gangan to ti fohun
 • Ologo to ju ogo to ni
 • Mimo kabiyo osi emi o je fi osere, afi eni to be
 • Fegba query lido re
 • Mi o je fo ju di o
 • Oba to o se wo loju wo
 • O ti e leti ai le dibaje ni o
 • Baba nla ku baba mi
 • O le pi yikin
 • Mimo
 • Gbogbo eni to be mi riri oluwa e teriba ewa riri fun oba tite re ki si
 • Ibere at opin, Olorun ajanaku, tin mi gbo kijikiji mimo
 • Tabubu, tale bu tan, pupo si no gbogbo ojo
 • Eje ka sale fun oba rere taba mo riri
 • Emi inu awon woli
 • Atobitan, alainiye, popo koja riri
 • Terere koja kika,
 • Ailetuwo, adaun ro, adaun se, adaun so
 • Oluwa inu awon orun oke nla arogunmatidi
 • Arabaribiti aribirabata
 • Ejinkota biko yingirin
 • Oke o le sa, oke o le he
 • Koseni to le no aditu re, olodumare
 • Iwo lo di Iwo lo le tu oba nla gbogbo
 • Agbaye loun
 • Teriba fun baba o agba

Gbangban gbangban jaranjaran fenfefenfe
Iba o iba
Iwo lodi iwo lo le tu
Obanla gbogbo agbaye loun teriba fun o
Baba agba
Gbangban gbangban jaranjaran fenfefenfe
Iba o iba

See Also : Omo Baba By Spirit of Prophecy

Mimo Loluwa
Mimo
Angeli won mi ke
Awon orun mi ke
Mimo
Egbageje irawo
Mimo

Tope Alabi Mimo Loluwa Oba Ara Video

Be the first to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published.


*